Omo igbala leti oja tin nwo gere-re
Omo Ajo lori owo
Omo ajegegbadi
Omo o pa ekun, pa ere
Omo ala bii re
Omo ilemi san mi
Eni ara bari ko ba tie lo
Omo oni yan koko ti nte egbe isu
E ki binu, eki onigbajamo
Omo olodo ide
Omo ijesha dudu legbon
pupa la buro
Omo ile niawa ti nmu ina roko
Omo owa omo obokun
Omo onitolu ajina
Omo aborisa se ile
Omo papanla soju rahurahu
Ogede gbomo pon se bi egungun
Omo Adele Olu Okidi alaseju bi
omigbigbona
Okiti gbona gijan gijan
O joye tan fa ebi e modo
Signage vol.1 No1
21